Gomina Ademọla Adeleke di Aṣiwaju ilu Ẹdẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gbogbo eto lo ti to bayii lati fi Gomina ipinlẹ Ọṣun, Sẹnetọ Ademọla…

Ọpẹ o! Awọn akẹkọọ Fasiti Kogi ti wọn ji gbe ti gba itusilẹ

Monisọla Saka Ori ti ko awọn akẹkọọ ileewe giga Confluence University of Science and Technology, Osara,…

Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ si Lalaa onitiata

Faith Adebọla Bi olorin atijọ kan ṣe kọ ọ, ‘iya ni wura, baba ni digi, ọjọ…

EFCC ya bo ilu  Ẹdẹ, ọmọ Yahoo mẹrinlelọgọta ni wọn ko

Faith Adebọla  Niṣe lọrọ di ẹni ori yọ o dile laarin awọn afurasi ọdaran ti wọn…

Ere agbere: Ẹ wo ohun tawọn akẹkọọ Fasiti Kogi ṣe fun olukọ wọn

Faith Adebọla  Olukọ kan ni fasiti ijọba apapọ, Federal University to wa niluu Lọkọja, nipinlẹ Kogi, ko ni i…

O ma ṣe o! Eeyan meji ku nibi tanka epo to gbina l’Ekoo

 Monisọla Saka Eeyan meji lo ti ṣe bẹẹ pade iku ojiji, lasiko ti tanka epo kan…

Ọdaju abiyamọ: Abikẹ ji ọmọleewe kan gbe l’Ọbada-Oko, lo ba ta a soko-ẹru ni Libya

Faith Adebọla  Ọwọ awọn agbofinro ipinlẹ Ogun ti tẹ ọdaju abiyamọ kan, Abikẹ Ọlọnade, niṣe lo…

Sikiọriti ji mọto ọga ẹ, nibi to ti fẹẹ ta a ni gbanjo ni wọn ti mu un

Faith Adebọla  Ọwọ palaba gende-kunrin kan ti wọn gba gẹgẹ bii ọlọdẹ lati maa daabo bo…

Iru ki leyi! Taiwo bọọlẹ lati ṣi geeti wọle, lawọn adigunjale ba wa mọto rẹ lọ tọmọtọmọ n’Ikẹnnẹ

Faith Adebọla Inu ibanujẹ gidi, adanu ọna meji ni baale ile kan, Taiwo Fayọbi wa bayii…

Wahala wa o! Awọn ọdẹ to n ṣọ fasiti aladaani yii fipa ba akẹkọọ sun

Ọlawale Ajao, Ibadan Inu ibanujẹ lọpọ awọn akẹkọọ atawọn alaṣẹ fasiti aladaani kan, Ajayi Crowther University…

Nitori to digunjale, adajọ ni ki wọn lọọ yẹgi fun Friday l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ile-ẹjọ giga to fi ikalẹ siluu Akurẹ, ti ni ki wọn lọọ yẹ…