Monisọla Saka Ọgbẹni Adekunle Agunbiade, ti i ṣe ọkan lara awọn fijilante to n ṣọ adugbo…
O ti dofin o, ẹwọn taara ni ẹni to ba ji ina ijọba lo n lọ l’Ọṣun
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ileeṣẹ to n pin ina ijọba ni ẹkun Ibadan, Ibadan Electricity Distribution Company…
Nitori bi ileeṣẹ IBEDC ṣe ja ina wọn, awọn oṣiṣẹ ileewosan UCH fẹẹ daṣẹ silẹ n’Ibadan
Ọlawale Ajao, Ibadan Afi ki gbogbo ẹni to ba ni alaisan to n gbatọju nileewosan ijọba…
Ọba Ẹlẹkọle ti Ikọle dawati laafin, ni gbogbo ara ilu ba n jaya
Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ibẹru ati ipaya lo wa lọkan awọn eeyan ilu Ikọle-Ekiti, nijọba ibilẹ Ikọle,…
Gọngọ sọ nile-ẹjọ lasiko igbẹjọ ti awọn aafaa Ilọrin pe Saheed Shittu waye
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kẹtadinlọgbọn, oṣu Kẹta, ọdun 2024 yii, nile-ẹjọ Upper Area, to…
Gomina Adeleke fẹẹ ṣatunṣe awọn ileewe ẹkọṣẹ ọwọ to wa l’Ọṣun
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina Ademọla Adeleke ti sọ pe gbogbo awọn ileewe ẹkọṣẹ ọwọ mẹsẹẹsan to…
Nitori Bobrisky, ija nla bẹ silẹ laarin awọn oṣere tiata, epe ni wọn n gbera wọn ṣẹ
Faith Adebọla Ni bayii, ina ija to n jo bulabula laarin awọn oṣere tiata ilẹ wa,…
Baale ile yii gbe majele jẹ nitori ti ọrẹbinrin rẹ n yan ale
Adewale Adeoye Baale ile kan, Oloogbe Kelvin Mhofu Ngoshi, ọmọ orileede Zimbabwe, ṣugbọn to n gbe lorileede South Africa, lo ti gbẹmi…
NAFDAC ti awọn ileeṣẹ burẹẹdi ati ti piọ-wọta ti ko niwee ijọba pa
Adewale Adeoye Ajọ to n ri sohun jijẹ ati mimu lorileede wa, NAFDAC, ẹka ipinlẹ Rivers, ti ti awọn…
Ẹwọn gbere ni adajo ju baale ile to fipa b’ọmọ ọdun marun-un sun l’Ekoo si
Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Rahman Oṣhodi, tile-ejọ kan to n ri si ẹsun fifipa ba ọmọde sun ati lilo ọmọde nilokulo niluu Eko, ni wọ…
Adajọ ni ki wọn lọọ yẹgi fun oyinbo Chinese to pa ọrẹbinrin rẹ ni Kano
Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Sanusi Ado Ma’ aji, tileejọ giga kan to wa lagbegbe Bompai, nipinlẹ Kano, ni wọn foju oyinbo Chinese kan, Ọgbẹni…